Adeyinka Alaseyori – Ire Iran Download (Video,Lyrics, Mp3)
Contents
Based In African, Nigerian Gospel Music Minister Adeyinka Alaseyori Releases a New Song in August, 2021 Titled “Ire Iran” with Mp3 Download and Lyrics
This Song is an Undiluted Praise Medley that deserves your attention, Available on all digital platforms.
Mp3 Download for Ire Iran by Adeyinka Alaseyori
Ire Iran Lyrics
Awon kn ku
laisi imuse ileri
Olorun mi o fe
Awon kan feti gbo ileri titi kose
Sugbon ko pada se olorun
Ileri ti mogbo ninu bibeli
ateyi ti mo la loju ala
eyi ti mo ri ninu iran
ati isotele
Ire ire ire iran mi o tete se
Lori mi tete se maje nku kogo te de o
Ire iran o iran ire jo tete se mo mi lara o
Ire iran o iran ire jo tete se
Pataki pataki ni wipe imuse ileri
Akai moye ileri lati feti gbo ti o ba imuse pade o
Ida duro ileri idaduro ala tabi iran
Ole mu komo ologo ma rare o
Akoko imuse ileri o to
Ire iran se momi lara o
Gbogbo idile lo ni ire iran ati ibi iran
ei ati se tojewipe egun iran lo n tele opolopo kiri
Ire iran mi da o
akoko imuse mi ti de
Olohun wo lo ma ndahun adura o
Imuse ileri mi da o
Melo nigba to ti gbo poma travel owo local flight ri
Video
Adeyinka Alaseyori – Ire Iran Mp3 Download (Video, Lyrics)