Adeyinka Alaseyori Silekun Aanu [Download Mp3, Mp4, Lyrics]

Contents

Adeyinka Alaseyori Silekun Aanu [Download Mp3, Mp4, Lyrics]

Adeyinka Alaseyori Silekun Aanu [Download Mp3, Mp4, Lyrics]

Adeyinka Alaseyori Silekun Aanu [Download Mp3, Mp4, Lyrics]

Popular Nigerian gospel singer, Adeyinka Alaseyori is here with a popwerful new song “Silekun Aanu” From her Album Alaabo mi mi.

Meanwhile He has released great songs like, Aye ope yo, Arojinle, which is her most popular song, He made a way, Atobiju, faetuing Ola, with The Almighty God and severel life blessing songs

You can easily acess All Adeyinka’s song here

Kindly sit back, click on the play button to listen to the song and enjoy or you click the download button to get the audio for free.

Mp3 download for Silekun Aanu by Adeyinka Alaseyori

Download Mp3

Lyrics of the song

Talolomo tire tohun yo omo temi lenu
Ema dalekun emi mimo ada
Talo laye tire to ya ye temi lenu
Ema dalekun emi mimo ada

Talolomo tire tohun yo omo temi lenu
Ema dalekun emi mimo ada
Talo laye tire to ya ye temi lenu
Ema dalekun emi mimo ada

[Lead]
Talolomo tire tohun yo omo temi lenu
Ema dalekun emi mimo ada
Talo laye tire to n dutemi mo tire
Ema dalekun emi mimo ada

Talolomo tire tohun yo omo temi lenu
Ema dalekun emi mimo ada
(Ada wo lejo iku)
Talo laye tire to ya ye temi lenu
(Tan n nimilara)
Ema dalekun emi mimo ada

Adeyinka Alaseyori Silekun Aanu

[Intro]

[Lead]
Talolomo tire tohun yo omo temi lenu
Ema dalekun emi mimo ada
Talo laye tire to n dutemi mo tire
Ema dalekun emi mimo ada

[All]
Talolomo tire tohun yo omo temi lenu
Ema dalekun emi mimo ada
Talo laye tire to n dutemi mo tire
Ema dalekun emi mimo ada

Iwo mimo lo sowipe a o sure
Feni toba sure funmi
A o fija fawon to n bami ja
Lolorun awon omo Ogun so

Nikokora jo e korayin jo
Nitori ki ise toluwa ao
tun yi ka ao fayin ya pere pere

Nitori na Enikeni topinnun lati yaye mi lenu

Talolomo tire tohun yo omo temi lenu
Ema dalekun emi mimo ada
Talo laye tire to n dutemi mo tire
Ema dalekun emi mimo ada

Adeyinka Alaseyori Silekun Aanu

Eyin aanu so nimo mo
eyi ti aanu so ni mofi sagbara
eyi ti aanu so lo ri mi ati idile mi
Nipe Koni si ewu o

Eyin aanu so nimo mo
eyi ti aanu so ni mofi sagbara
eyi ti aanu so lo ri mi ati idile mi
Nipe Koni si ewu o

Eyin aanu so lori agbero ni wipe
Ko kuro lagbero ko wa lojoba lori ero
Eyi ti aanu so lori agan ni wipe
Ko kuro nipo agan kowa lo diya abiye
Eyi tia aanu so lori Olukuluku ni kia dimu nipe’Koni si ewu o

Ki lanu so lori yin..

Adeyinka Alaseyori Silekun Aanu

Eyin aanu so nimo mo
eyi ti aanu so ni mofi sagbara
eyi ti aanu so lo ri mi ati idile mi
Nipe Koni si ewu o

Opo Eniyan loti gba iroyin Dokita ju Tolorun lo
Ogun ebi won lofi nperawon loruko
Opolopo loti ni dati iku won lori
Won ti gbagbe pe enikan nbe toferan wa
Eni to n so HIV possitive di Negative

Eyi ti aanu so lomi ati idile mi nipe
Koni si ewu o

Eyin aanu so nimo mo
eyi ti aanu so ni mofi sagbara
eyi ti aanu so lo ri mi ati idile mi
Nipe Koni si ewu o

Adeyinka Alaseyori Silekun Aanu

[Intro]
[Bridge]
Am a Living testimony
A glorious destiny
A royal princehood
a chosen Nation
Ogo nimi o Nidile mi

[All and Adlib]]
Am a Living testimony
A glorious destiny
A royal princehood
a chosen Nation
Ogo nimi o Nidile mi

Am a Living testimony
A glorious destiny
Bebedi Odomu se dide ninu idile re laye
Ogo nimi o Nidile mi

Adeyinka Alaseyori Silekun Aanu

[All and Adlib]]
Am a Living testimony
A glorious destiny
A royal princehood
a chosen Nation
Ogo nimi o Nidile mi

Oluwa dide o Oluwa dide o
Oluwa dide o Oluwa ran mi lowo
Agbara mi nikan ogbe o Oluwa dide

Oluwa dide o Oluwa dide o
Oluwa dide o Oluwa ran mi lowo
Agbara mi nikan ogbe o Oluwa dide

[Lead]
Lojo ojokan loso Jabesi dayo
Lojo ojo kan losoro hanah Dayo
Lojo Oni o Oluwa soro mi dayo

[All]
Lojo ojokan loso Jabesi dayo
Lojo ojo kan losoro hanah Dayo
Lojo Oni o Oluwa soro mi dayo

[Lead]
Lojo ojokan loso Jabesi dayo
Lojo ojo kan losoro hanah Dayo
Lojo Oni o Oluwa soro mi dayo

Obedi odomu Okuro ninu ibanuje
Laarin osu meta osoo dolori ire
Eniti gbogbo aye fi bu itan re si yi pada
Lojo oni o Oluwa soro mi dayo

Oluwa dide o Oluwa dide o
Oluwa dide o Oluwa ran mi lowo
Agbara mi nikan ogbe o Oluwa dide

Adeyinka Alaseyori Silekun Aanu

Silekun Aaanu mi sile
Mofe gbenu ogo sogo
Silekun Aaanu mi sile
Mofe gbenu ogo sogo
Ilekun isere re mi kosi
Ilekun igbega mi kosi

Bojo se nlo kilekun mi ko ma si
Ohun re re o gbodo dewo mi tile tile
Silekun Aaanu mi sile
Mofe gbenu ogo sogo
Baba mofe gbenu ogo sogo
Mo fe pe ninu ogo
Baba mofe gbenu ogo sogo
Ayeraye
Silekun Aaanu mi sile
Mofe gbenu ogo sogo
Silekun Aaanu mi sile
oo oooo
Mofe gbenu ogo sogo

Download Mp4

Adeyinka Alaseyori Silekun Aanu

Video of the song

Adeyinka Alaseyori Silekun Aanu [Download Mp3, Mp4, Lyrics]

https://www.youtube.com/channel/UCsW8Uqu4WoRzoC0eCibq14Q

Adeyinka Alaseyori Silekun Aanu [Download Mp3, Mp4, Lyrics]

https://linktr.ee/gospellife

Follow Us On Facebook InstagramTwitter

Similar Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *