Apostle Daniel Ekunola - Adaba Mimo Emi Olulunu (Celestial Inspired Hymns 2) Mp3 Download

Apostle Daniel Ekunola – Kasise Fun Iwemimo (Celestial Inspired Hymns 2) Mp3 Download

Contents

Apostle Daniel Ekunola - Kasise Fun Iwemimo (Celestial Inspired Hymns 2) Mp3 Download

Based In Africa, Popular Gospel Music Minister Apostle Daniel Ekunola Releases a New Song in November, 2021 Titled “Kasise Fun Iwemimo (Celestial Inspired Hymns 2)” with Mp3/ Mp4 Download and Lyrics

This Song is an Undiluted Praise Medley that deserves your attention, Available on all digital platforms.

Mp3 & Audio Download for Apostle Daniel Ekunola – Kasise Fun Iwemimo (Celestial Inspired Hymns 2)

Download Mp3

Mp4 YouTube Video

Kasise Fun Iwemimo (Celestial Inspired Hymns 2) Lyrics

1: Ka sise fun iwenu mo emi wa,
K’Oluwa fi le wa pelu wa,
Ka sise fun Ijo Jehovah,
Ka si ranti orun mimo,
Ka sise fun iwenumo, emi wa,
Ka si ranti ile la loke orun,
Ka sise fun iwenumo, emi wa,
Ka si ranti ile la loke orun.

2: K’ Oluwa jowo sokale sarin wa,
Ka wa fi le ri iwenumo,
Michael Mimo kowa ran wa lowo,
Kuro ni nu idanwo aiye,
Ka wa fi le segun emi esu,
Ka sise pelu ife mimo,
Ka wa fi le segun emi esu,
Ka sise pelu ife mimo.

3: Asan ni fun enia lati f’okan fun,
Isura aiye ti yio fo lo,
O ye ka wa pejo ka sise,
Ise ti Kristi ran wa,
Eyi ni yio mu wa gb’ade Ogo,
Ti Baba se leri re fun wa,
Eyi ni yio mu wa gb’ade Ogo,
Ti Baba se leri re fun wa. Amin

Kasise Fun Iwemimo (Celestial Inspired Hymns 2) Mp3 Download

Follow Us On Facebook InstagramTwitter

Similar Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *