Bukola Bekes - Osuba Re {Olorun to lagbara}

Bukola Bekes – Ire (Goodness)

Contents

“Ire by Bukola Bekes (Goodness)” is a song by Popular and Talented singer and gospel music minister with Mp3, Lyrics, Mp4 and Video Download

This Song is an Undiluted Praise Medley that deserves your attention, Available on all digital platforms.

Bukola Bekes - Ire (Goodness)

Mp3 & Audio Download for Bukola Bekes – Ire (Goodness)

Download Mp3

Mp4 YouTube Video

Bukola Bekes – Ire (Goodness) Lyrics

Ire/3* Nile mi ooo
moo rire gba
lowo oluwa…
Ayo mi kun
EBA mi joo

Jesu ti soro mi dayo(2) verse1: Hallelujah idemi ja hallelujah mo bori Ogun ese hallelujah moju asegun lo ororo Ayo on San nilewa. chorus…….(2)
verse2
Sugbon kan nbe laye mi
emi ko femo lato niloo

ire lotun ire losi
he kowa mi ri oooo
eledunmare
maje ori wa gbabode.(2). chorus…..(2).
hymn…. mosinmi le jesu ninu Igbi aye
ire ire ire ire
….,……….,,,,,, ire Ayo
ire Ayo kowa sodo mi
nitoripe
iba nuje kosi loro mii
moodupe
call & rsp
Gbani gbani gbani oo(4) Gbani (4).
Gbagba gba ni to asaa ba
Ogbeja keru o bori eni too Nija
olori aye gbogbo…ooo

Call: Nitori pe agan to kepe oluwa
RSP: Ennnnnnnn…..
Oromo gbejo
ennnnnnmm
afoju to kepe oluwa
Nise loo riran
Aro to keep oluwa
kikia kia lodide koun
Obirin Oni sun eje kepe jesu
Isun eje gbe
notori na
kepeleda ree(2) akuku she tire Olorun iyanu 3
aba o she oooo

Mogbagbo olorun iyanu
aba o see(2) Toripe koma salagbara biire(2)
olorun iyanu (2) Aba o see. (repeat). Aso one isoro re di petele Olorun alewi lese olorun adegboye. toripe koma salagbara biire re ….. 2
olorun iyanu (2*) repeat.
Asoroko bi ogiri oke
Awi mayewun
Asoro ma taste
asoro maybe
oji lasaru oku ojo kerin dide

Leave a comment Below on “Bukola Bekes – Ire (Goodness)”

Follow Us On Facebook InstagramTwitter

Similar Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *