C.A.C Good Women Choir - Odun Yi Atura Mp3 Download

C.A.C Good Women Choir, Ibadan – Halleluyah Lo Mu Mi Goke Lyrics, Mp3 Download

Contents

C.A.C Good Women Choir, Ibadan - Halleluyah Lo Mu Mi Goke Lyrics, Mp3 Download

Based In African, Popular Gospel Music Minister C.A.C Good Women Choir, Ibadan Releases a New Song in September, 2021 Titled “Halleluyah Lo Mu Mi Goke” with Mp3/Mp4 Download and Lyrics

This Song is an Undiluted Praise Medley that deserves your attention, Available on all digital platforms.

Mp3 & Audio Download for C.A.C Good Women Choir, Ibadan – Halleluyah Lo Mu Mi Goke (Mrs D.A. Fasoyin)

Download Mp3

Mp4 YouTube Video

 

Halleluyah lo mu mi goke mo dupę
Halleluyah lo mu mi goke ninu ewu
Halleluyah lo mu mi goke m’awôn ôta lôwô
Halleluyah lo mu mi goke odo
Halleluyah lo mu mi goke mo dupę
Halleluyah lo mu mi goke ninu ewu
Halleluyah lo mu mi goke m’awôn ôta lôwô
Halleluyah lo mu mi goke odo
Ota alôrę, t’o n f’ôrô mi wa lô kiri

Wôn rele adahunse, wôn rele onisegun
Sugbôn ępa ko b’oro mô, wôn p’ete p’ero
wipe k’omi aye gbe wa lô
Igi a ba f’ęyin ti, gbogbo rę ęgun lo ję
Ęni t’ani k’o f’ęni l’oju tun f’ata s’ęnu
Owu kii da k’inu o b’oloko
Gbogbo aja ki p’aja, kikan agbo ki p’agbo ę ję n j’isę Ba mi
Itakun t’o ni k’erin ma goke alô o ti tę
Ôba t’o gbe Mose n’ija, Oun lo mu wa bori
Halleluyah lo mu wa goke m’awôn ôta lôwô

Halleluyah lo mu wa goke ayô
Halleluyah lo mu mi goke mo dupę
Halleluyah lo mu mi goke ninu ewu
Halleluyah lo mu mi goke m’awôn ôta lôwô
Halleluyah lo mu mi goke odo
Ninu iwe mimô, awôn t’an ke wôn ti d’asegun
Iwô ke pęlu, wô yo si bori ogun
Ômô Israęli, n’igba ti wôn jade l’oko ęru Mose n ko wôn lô Kenani, n’ilę ileri
Okun pupa niwaju, ogun Farao l’ęyin
Awôn ęlęsin, atawôn ômô-ogun gbiyanju lati ko awôn ômô Israęli l’ęru
Isę Oluwa iyanu ni, iyanu ni
Ôrô Oluwa iyanu ni, iyanu ni
Ôna Oluwa iyanu ni, iyanu ni
Ômô Israęli kôja l’ori iyangbę ilę
Ogun Farao s’egbe s’inu okun pupa
Halleluyah l’orin ayô l’ôjô na

Halleluyah lo mu wôn goke m’awôn ôta lôwô
Halleluyah lo mu wôn goke odo
Halleluyah lo mu mi goke mo dupę
Halleluyah lo mu mi goke ninu ewu
Halleluyah lo mu mi goke m’awôn ôta lôwô
Halleluyah lo mu mi goke odo
Oluwa t’o gba Danięli l’ôwô kinihun, ko le s’ai gbô t’emi dandan lati ko mi yô
Oun lo gba Heberu męta ‘nu ina ileru
Oun lo gbô ti Jona pęlu latinu ęja
Awôn ęlęri eke dide si mi Oluwa
Iwô t’o gbô t’Elijah, ma s’ai gbô t’emi Baba
Dide Oluwa, se ‘dajô f’awôn eke arakunrin
Dide Oluwa, se ‘dajô f’awôn eke arabinrin
Iwô to gbe Josęfu n’ija, ba mi d’oju ti wôn l’aye

Ôta n lulu ibaję, Oluwa ni ko ję o dun
Halleluyah ko mu mi goke m’awôn ôta lôwô
Halleluyah ko mu mi goke odo
Halleluyah lo mu mi goke mo dupę
Halleluyah lo mu mi goke ninu ewu
Halleluyah lo mu mi goke m’awôn ôta lôwô
Halleluyah lo mu mi goke odo
Ipinya le de l’aye, sugbôn ayô ni l’ôrun
K’a le jô wa titi pęlu awôn mimô to ti lô
Ipinya le de l’aye, sugbôn ayô ni l’ôrun
K’a le jô wa titi pęlu awôn mimô to ti lô
Halleluyah l’orin ti wôn nkô niwaju Baba
Halleluyah, orin isęgun f’awôn to gbagbô
Paulu, Sila ke ninu tubu ide wôn si ja
Iwô t’ôna rę ba r’uju, iwô t’aye ni l’ara
Halleluyah l’orin tiwa (Halleluyah l’orin tiwa)

Halleluyah l’orin tiwa (Halleluyah l’orin tiwa)
Awôn afôju ke, wôn riran (Halleluyah l’orin tiwa)
Ayarô ke, o fo f’ayô (Halleluyah l’orin tiwa)
Agan ke o si d’ôlômô (Halleluyah l’orin tiwa)
Awôn ôta gbô wôn si sa (Halleluyah l’orin tiwa)
Ogun esu gbô o si sa (Halleluyah l’orin tiwa)
Awôn aję gbô wôn si sa (Halleluyah l’orin tiwa)
Halleluyah lo mu wa d’ęru m’awôn ôta lôwô
Halleluyah lo mu wa goke odo
Halleluyah lo mu mi goke mo dupę
Halleluyah lo mu mi goke ninu ewu
Halleluyah lo mu mi goke m’awôn ôta lôwô
Halleluyah lo mu mi goke odo

C.A.C Good Women Choir, Ibadan – Halleluyah Lo Mu Mi Goke Lyrics, Mp3 Download

Follow Us On Facebook InstagramTwitter

Similar Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *