Contents
“Baba Toto Baba of First Baptist Church Okelerin” is a song by Popular and Talented singer and gospel music minister with Mp3, Lyrics, Mp4 and Video Download
This Song is an Undiluted Praise Medley that deserves your attention, Available on all digital platforms.
Mp3 & Audio Download for First Baptist Church Okelerin – Baba Toto Baba
First Baptist Church Okelerin – Baba Toto Baba Lyrics
baba to to baba
Olorun to le loju Ogun
Eyin Niyin Yeh eh
Eyin lope to si
baba to to baba
Olorun to dira Loju Ogun
baba yi ju baba lo
Akoni ni
baba to to baba
Olorun to le loju Ogun
Eyin Niyin Yeh eh
Eyin lope to si
baba to to baba
Olorun to dira Loju Ogun
baba yi ju baba lo
Akoni ni
Jehovah soba oh
Olorun baba Ogun ni
Jehovah soba oh
Olorun baba Ogun ni
Ohun ni Oba Ogun
Jehovah soba oh
Olorun baba Ogun ni
Owo kenbe rebi ija
Olorun to johun taye molo
Iwo lawa yio ma sin
Titi lailai
Oro baba Oro
Owo re ka gbogbo aye atorun
Fowo agbara re taye wa se baba rere
Owo kenbe rebi ija
Olorun to johun taye molo
Iwo lawa yio ma sin
Titi lailai
Oro baba Oro
Owo re ka gbogbo aye atorun
Fowo agbara re taye wa se baba rere
Jehovah soba oh
Olorun baba Ogun ni
Jehovah soba oh
Olorun baba Ogun ni
Ohun ni Oba Ogun
Jehovah soba oh
Olorun baba Ogun ni
baba to to baba
Olorun to le loju Ogun
Eyin Niyin Yeh eh
Eyin lope to si
baba to to baba
Olorun to dira Loju Ogun
baba yi ju baba lo
Akoni ni
baba to to baba
Olorun to le loju Ogun
Eyin Niyin Yeh eh
Eyin lope to si
baba to to baba
Olorun to dira Loju Ogun
baba yi ju baba lo
Akoni ni
Vamp: Mogboruko re ga, Mogboruko re ga
Mogboruko re ga, Mogboruko re ga
Akoni lo je loju ija, mofida mi lele mo yin o
Agbara je ti re, Mo gboruko re ga
Oba to n finan soro, Jagunjagun to n gbori ite
Ajagunsegun masese, Olorun agbeja
baba to to baba
Olorun to le loju Ogun
Eyin Niyin Yeh eh
Eyin lope to si
baba to to baba
Olorun to dira Loju Ogun
baba yi ju baba lo
Akoni ni
Jehovah soba oh
Olorun baba Ogun ni
Jehovah soba oh
Olorun baba Ogun ni
Ohun ni Oba Ogun
Jehovah soba oh
Olorun baba Ogun ni
Leave a comment Below on “First Baptist Church Okelerin – Baba Toto Baba”
Click here to Download Audio Download Mp3
Pls d tonic solfa of dis song