Contents
Igba otun tide Song by Akin Adebayo
Akin Adebayo has just released a new track. Listen and Download Below
Here is the Lyrics of the Igba Otun tide Song by Akin Adebayo
Igba otun ti de wa rerin ayo oh Oju ko ni ti o. ka sama gbadura boti wu ki iji aye tole to adura lo le se sogbo.
Ori rere ori ayo lori oh igba gbogbo sa layo mi ire ni mofe lato ni lo oun re re ni yo ya lodo mi
igba otun ti de wa rerin ayo oh Oju ko ni ti o. ka sama gbadura boti wu ki iji aye tole to adura lo le se sogbo. Ori rere ori ayo lori oh igba gbogbo sa layo mi ire ni mofe lato ni lo oun re re ni yo ya lodo mi
Follow Us On Facebook InstagramTwitter