Kay Wonder - Olorun Ti A ko Ri
| |

Kay Wonder – Olorun Ti A ko Ri

Contents

Nigerian Talented music sensation, “Kay Wonder” releases a spirit lifting jam titled “Olorun Ti A ko Ri” his latest song in 2022.

“Olorun Ti A ko Ri” is available on all digital platforms for Free Download.

Kay Wonder - Olorun Ti A ko Ri

Mp3 & Audio Download for Kay Wonder – Olorun Ti A ko Ri

Download Mp3

Mp4 YouTube Video

Lyrics: Olorun Ti A ko Ri by Kay Wonder

Olorun tawa o ri
ta n rise re
Olorun tawa o ri
ta n rise re
Ari lara Okun ato sa
Ari lara Ofurufu Olorun tawa ori
ta nri ise re

Olorun tawa o ri
ta n rise re
Olorun tawa o ri
ta n rise re
Ari lara Okun ato sa
Ari lara Ofurufu Olorun tawa ori

Oforun Joba Osan, Ofosupa joba oru
Oforun Joba Osan, Ofosupa joba oru
Pelu kiki Oro re Kiki agbara
On gbe ile aye sori agbami
Eni ti iri re dabi iro iji
Akoyin sire bi mona mona
Ani aye raye
Latowo re ni

Olorun tawa o ri
ta n rise re
Olorun tawa o ri
ta n rise re
Ari lara Okun ato sa
Ari lara Ofurufu Olorun tawa ori
ta nri ise re

Oba to je o
taye torun mi titi
Kile ole se
tale oju lo
Oba to je o
taye torun mi titi
Kile ole se
ato fara ti

Ki le o le se
tale oju lo
Ki le o le se
tale oju lo
Oba to je taye torun
Mi ti
Ki l o le se Ato farati

Ari lara Okun ato sa
Ari lara Ofurufu Olorun tawa ori
ta nri ise re
Ari lara Okun ato sa
Ari lara Ofurufu Olorun tawa ori
ta nri ise re

Ari lara Okun ato sa
Ari lara Ofurufu Olorun tawa ori
ta nri ise re
Ari lara Okun ato sa
Ari lara Ofurufu Olorun tawa ori
ta nri ise re

Make Sure You enjoy and Share “Olorun Ti A ko Ri”

Follow Us On Facebook InstagramTwitter

Similar Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *