Mr Gbera - Iru Iriri ft. Adeyinka Alaseyori

Mr Gbera – Iru Iriri ft. Adeyinka Alaseyori Download (Lyrics,Video, Mp3)

Contents

Mr Gbera - Iru Iriri ft. Adeyinka Alaseyori

Based In African, Popular Gospel Music Minister Mr Gbera Releases a New Song in September, 2021 Titled “Iru Iriri ft Adeyinka Alaseyori” with Mp3 Download and Lyrics

This Song is an Undiluted Praise Medley that deserves your attention, Available on all digital platforms.

Mp3 Download for Iru Iriri by Mr Gbera ft. Adeyinka Alaseyori

Download Music

Iru Iriri Lyrics ft Adeyinka Alaseyori

Eyi to jababara fun won
sebohun lofi sara fun wo
Iru iriri ti mori gba won kori
Sugbon anu ti morigba woko ri gba

Ohun gbogbo to jababara fun won
sebohun lofi sara fun wo
Ohun toje ipalara fun won
ara irelofi jasi femi
tori moranugba ni

Ohun to lakoja to fa eri
lofa iku opolopo
oje dupe

Ona to hun lo to nmu onje wale
lomu opo lo orun oje dupe
Ona ofun re oda ona iku
oje dupe
Omo tori gbedani ohun logba emi opolopo oje dupe

Iru iriri ti mori gba la won kori
Sugbon anu ti morigba woko ri gba

Iru iriri ti mori gba la won kori
Sugbon anu ti morigba woko ri gba

Orisirisi iriri lohun sele
Aimoye nkan ta ogbori losele
Gbogbo orile ede ohun be ni titi

Iru iriri ti mori gba la won kori
Sugbon anu ti morigba woko ri gba

Mp4 Video

Mr Gbera – Iru Iriri ft. Adeyinka Alaseyori Download (Lyrics,Video, Mp3)

Follow Us On Facebook InstagramTwitter

Similar Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *