Ola Best - Ko S'Ogun Ye Ft. Shola Sax Download (Lyrics,Video, Mp3)

Based In Africa, Nigerian Gospel Music Minister Ola Best Releases a New Song in October, 2021 Titled “Ko S’Ogun Ye Ft. Shola Sax” with Mp3/ Mp4 Download and Lyrics

This Song is an Undiluted Praise Medley that deserves your attention, Available on all digital platforms.

Mp3 & Audio Download for Ola Best – Ko S’Ogun Ye Ft. Shola Sax

Download Mp3


Click here to Download Audio


Mp4 YouTube Video

Ko S’Ogun Ye Lyrics Ft. Shola Sax

So many times God
I’m always thinking hard
Why you love me so te
O jẹ kin ṣaye wa oo
Awọn ọta mi try so much
Buy wọn o ri mi ba
Kinni ma fi fun ọ oo Jesu
Afi kin mọpe wa oo

Ẹni to ti ki o lori meji
Awọn to mbẹ lewọn o sẹ ọ Oluwa mi
Some people dey hospital lọwọ lọwọ bai
Gba iyin gba ogo lori aye mi toripe

Ko s’ogun ye, Otiku
Ko s’ogun ha, nibo lo lọ
Ko s’ogun kawọ leri fẹsẹ janlẹ
E ma ṣe oo baba
*2

Sax solo

Many many are the afflictions of the righteous
But the Lord God deliver us from them all
Ipa awọn ẹni ibi aye iba ti bo mi mọlẹ
Ọba ton jẹbi Àra lo bami fi ina jo wọn pale

Mo jagun Ajaye ,ajaga mi bọ
Mo r’anu gba lọwọ baba mimọ
Abo rẹ lori aye mi ẹnu o le sọ̀
Infact lori ẹbi ,ara ,ati ojulumo oo

Ko s’ogun ye, Otiku
Ko s’ogun ha, nibo lo lọ
Ko s’ogun kawọ leri fẹsẹ janlẹ
E ma ṣe oo baba
*2

Call .. addlibs
Response.. Ẹ ma ṣe oo baba (repeat)

Ola Best – Ko S’Ogun Ye Ft. Shola Sax Download (Lyrics,Video, Mp3)

Click here to Download Audio
Download Mp3

Leave a Comment

Your email address will not be published.