Olusolade Oyetunde – Ìre Odún Tuntun Download (Lyrics,video, Mp3)
Contents
Based In Africa, Popular Gospel Music Minister Olusolade Oyetunde Releases a New Song in September, 2021 Titled “Ìre Odún Tuntun” with Mp3/Mp4 Download and Lyrics
This Song is an Undiluted Praise Medley that deserves your attention, Available on all digital platforms.
Mp3 & Audio Download for Ìre Odún Tuntun by Olusolade Oyetunde
Ìre Odún Tuntun Lyrics
Chorus:
Odún to n bo, a ba mi laye o
Ire gbogbo a je titemi
Loruko Jesu mi o ni sokun o
Ninu Odún tuntun, ayo laraye a ba mi yo.
Olorun to da aye, a fadun soro mi
Gbogbo ikoro patapata, a bami mu kuro
Lori oko, lori omo, ayo mi a po so
Ninu odun tuntun, ayo l’araye a ba mi yo.
Iro ayo la o ma gbo ninu ago mi
Gbogbo ona to ti wo, l’Olorun a ba mi to
Anito, aniseku, ninu ile mi
Ninu odun tuntun, mi o ni salaini o.
Ninu odun tuntun eyi, maa mo Olorun si
Ati se ife Olugbala, ko ni nimilara
Igbe aye emi mi, a maa dagba so
Ninu odun tuntun, aye mi a yin Olorun l’ogo.
YouTube Mp4 Video
Loading video
Olusolade Oyetunde – Ìre Odún Tuntun Download (Lyrics, video, Mp3 and mp4)
Follow Us On Facebook InstagramTwitter