Shola Allyson Lori Ileyi [Download Mp3, Mp4, Lyrics]

Shola Allyson Lori Ile yi [Download Mp3, Mp4, Lyrics]

Contents

Shola Allyson Lori Ile yi [Download Mp3, Mp4, Lyrics]

Shola Allyson Lori Ileyi [Download Mp3, Mp4, Lyrics]

Shola Allyson Lori ile yi [Download Mp3, Mp4, Lyrics]

Sensational Nigerian gospel singer, and song writer, Shola Allyson is here with another great song Lori Ile yi.

This song is part of Shola Allyson Old Songs. She has also released songs like, Aseye, Mimo, Ebe, wa wole, Isinmi, and other great songs.

When the world fails, music never do, it always keeps us going, GOSPEL is the answer and GOSPELLIFE is the platform

Kindly sit back, click on the play button to listen to the song and enjoy or you click the download button to get the audio for free.

Mp3 download for Gbeje Fori by Shola Allyson

Download Mp3

Lyrics of the song

Lori ile yi o
Oti sori ire
Lori ile yi o
Oti jeniyan
Lori ile yi o
Oti lowo lowo
Alale ile yi o bami fasesi

Lori ile yi o
Oti sori ire
Lori ile yi o
Oti jeniyan
Lori ile yi o
Oti lowo lowo
Alale ile yi o bami fasesi

Olorun bukun Naijiria Kale ri ire mu
Wara ati oyin to ti nsan
Kori sun re tun si
Ire kopadade sori ile wa
Alale ile jowo bawa se
Kosi o kase ni Naijiria
ma je ari iyan mo orara
Adede o gbenu mi sase Kori ile yi o
Kose igbe

Shola Allyson Lori Ile yi

Lori ile yi o
Oti sori ire
Lori ile yi o
Oti jeniyan
Lori ile yi o
Oti lowo lowo
Alale ile yi o bami fasesi

Baba rokun baba rosa
ile gan gan nile nje
Mofe roko mofe rajo
ile gangan labo simi oko
Kori gbere koni nibi taba wa
Iye gangan lose koko
Naijiria yi o asan wa sire
Kani suuru eyi to lojo

Lori ile yi o
Oti sori ire
Lori ile yi o
Oti jeniyan
Lori ile yi o
Oti lowo lowo
Alale ile yi o bami fasesi

Ironu oda nkan
Tete kawo kuro leran
Abamo oda nkankan
Ibi ori danisi la ngbe
Temi tre lajose
Odowo wa takotabo
Agbajo owo la fi nsoya
Jeji owo kan oda nkankan
Ogberu dori kasowope katunse
Eledumare akunwa lowo

Lori ile yi o
Oti sori ire
Lori ile yi o
Oti jeniyan
Lori ile yi o
Oti lowo lowo
Alale ile yi o bami fasesi

Eleya meya oyewa rara
Ifowo sowopo lo se koko
Oye Eledumare to kowa po
Isokan wa ma lo nfe
Alumoni wa koma ma ya wa
Olorun fun wa po ni
Ibi ife wa layo ngbe
Ibi ayo wa ire awaOlorun bukun ile wa
Emama je afayo fo

Shola Allyson Lori Ile yi

Lori ile yi o
Oti sori ire
Lori ile yi o
Oti jeniyan
Lori ile yi o
Oti lowo lowo
Alale ile yi o bami fasesi

Enitomi jaja esin ija arare lo ngbe
Olorun obere Olu gbe ja
Ohun to dawa mara to nda
Alafia wa malo nfe katun gbaye sogo
Fun igbagbo Musulumi Alabalaye
Olorun kan la nkesi
Kasowopo ka bebe si Ko le pada ye gbogbo wa

Lori ile yi o
Oti sori ire
Lori ile yi o
Oti jeniyan
Lori ile yi o
Oti lowo lowo
Alale ile yi o bami fasesi

Ironu oda nkan
Tete kawo kuro leran
Abamo oda nkankan
Ibi ori danisi la ngbe
Temi tre lajose
Odowo wa takotabo
Agbajo owo la fi nsoya
Jeji owo kan oda nkankan
Ogberu dori kasowope katunse
Eledumare akunwa lowo

Shola Allyson Lori Ile yi

Lori ile yi o
Oti sori ire
Lori ile yi o
Oti jeniyan
Lori ile yi o
Oti lowo lowo
Alale ile yi o bami fasesi

Alale ile yi o bami fasesi ire wa kokari
Alale ile yi o bami fasesi

Iwo todawa sapa ibi omara tofefi wa da
Alale ile yi o bami fasesi

Bawa fase soro wa ka gbori ile yi se rere
Alale ile yi o bami fasesi

Baase nwa ni kamari, baase nri ni koma towa lowo
Alale ile yi o bami fasesi

Baase nlu ni koma dun komama ya mowa lowo a bebe
Alale ile yi o bami fasesi

Ka gbori ile yi se rere sun wa siwa ju suwa siwaju
Alale ile yi o bami fasesi

Olowo mekunnun ara owu wa lofi wa nda
Alale ile yi o bami fasesi

Eni tonile maa gbo bawa fase si ire wa
Alale ile yi o bami fasesi
Oju aanu re o lababe siju aanu wo wa
Alale ile yi o bami fasesi

Alale ileyi o bawa fasesi
Alale ileyi o bami fasesi

Shola Allyson Lori Ile yi

Download Mp4

Shola Allyson Lori Ile yi

Video of the song

Shola Allyson Lori Ile yi [Download Mp3, Mp4, Lyrics]

Hope you enjoyed the song, If you really did kindly leave a comment to share your though and kindly share the song with your family and loved ones.

Shola Allyson Lori Ile yi

https://www.youtube.com/channel/UCsW8Uqu4WoRzoC0eCibq14Q

https://linktr.ee/gospellife
Shola Allyson Lori Ileyi song download and other old song.

Follow Us On Facebook InstagramTwitter

Similar Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *