It seems we can’t find what you’re looking for. Perhaps searching can help.
Oniduro mi ese ooo
Agejo ro mi ema se ooo
Boje niyan lohun duro ni
Wa ti ma soro
Boje niyan lohun duro ni
wa ti ma sin regun
Kiise mi mose
Kiise agabara mi kiise titobi mi
lese dai si o baba
Asiri to hun gaba yiti Yiti ninu osumare agbe oga
Enikerin ninu ina aileru
Ogo tohun wonu ofo eniyan to hun mogo jade
Ogo toka le sinu eni toje korofo to mogo ja gbangba
Ina saju re soju ogun ojo gbogbo awon ota re run
Iwo topase pe ki ina jo lori igbe ti igbe osi run
Ina loju ina lenu enikerin ninu ina aileru
orogun gbogun mi
Oba topase awe fawon kinuhun Ninu iwo kinihun
Leyin awe olojo meta o
Ope lamuwa iyin lamuwa Ounje yin lamu wa
Ki ise nipa iwa mino
Mowa dupe ore atodun modun
Mowa dupe ore igba kugba
Mowa dupe ore igba gbogbo
Ala tawon omo wa nla lojo
Awa tolorun ji saye esope ose
Tope Alabi and Tope Flourish also sang the song
It seems we can’t find what you’re looking for. Perhaps searching can help.