0

Yinka Ayefele – Hymns


“Yinka Ayefele – Hymns” is a song by Popular and Talented singer and gospel music minister with Mp3, Lyrics, Mp4 and Video Download

This Song is an Undiluted Praise Medley that deserves your attention, Available on all digital platforms.

Yinka Ayefele - Hymns

Mp3 & Audio Download for Yinka Ayefele – Hymns

Download Mp3


Click here to Download AudioMp4 YouTube Video

Loading

Hymns Lyrics

Oluwa ni apata wa
Aya re lawa osa si
Ewu ko wu ewu towu ki ode
Abo ninu iponju
Jesu ni apata awon alare
Fun alare
Jesu ni apata awon alare
Fun alare
abo ninu Iji iponju

Kosun wa lati ma kori ti Igbani
Ogo foloru Hallelujah
Awa yio figbagbo korin na soke
Ogo folorun Hallelujah
Omo Olorun ni eto
Lati ma busayo
Pe ona yi nyewa si
Okan wa nsaferi re
Nigbose se ao de afin
Obawa Ologo
Ogofolorun Hallelujah

Eje ka fi inu didun
Yin Oluwa Olore
Anu re owa titi
Lododo daju daju

Leave a comment Below on “Hymns”

Click here to Download Audio
Download Mp3 Follow Us On Facebook Twitter Instagram