Debra Crown-Olu - Korin Si Oluwa ft. Laolu Gbenjo (Lyrics, Mp3 Download)

Debra Crown-Olu – Korin Si Oluwa ft. Laolu Gbenjo (Lyrics, Mp3 Download)

Contents

Debra Crown-Olu - Korin Si Oluwa ft. Laolu Gbenjo (Lyrics, Mp3 Download)

Based In African, Popular Gospel Music Minister Debra Crown-Olu Releases a New Song in September, 2021 Titled “Korin Si Oluwa ft. Laolu Gbenjo” with Mp3 Download and Lyrics

This Song is an Undiluted Praise Medley that deserves your attention, Available on all digital platforms.

Mp3 Download for Korin Si Oluwa by Debra Crown-Olu ft. Laolu Gbenjo

Download Music

Korin Si Oluwa Lyrics ft. Laolu Gbenjo

Chorus:
Emi o kọrin si OLUWA, nitoriti o pọ̀ li ogo:
ẹṣin ati ẹlẹṣin on li o bì ṣubu sinu okun pupa.

1. OLUWA li agbara ati orin mi,
on li o si di ìgbala mi:
eyi li Ọlọrun mi, emi o si fi ìyin fun u;
Kabioyesi mo se iba re
Emi o kọrin si OLUWA,

Chorus:
Emi o kọrin si OLUWA, nitoriti o pọ̀ li ogo:
ẹṣin ati ẹlẹṣin on li o bì ṣubu sinu okun pupa.

2. Oluwa, li asà fun mi; ogo mi;
olugbe ori mi soke.
Emi fi ohùn mi kigbe si Oluwa,
o si gbohùn mi lati òke mimọ́ rẹ̀ wá.
Emi o kọrin si OLUWA,
Oba to ‘n be ninu orun

Response: gbega mi o le sai gbega titi lai.

O ran omo ni se fayati

Response: gbega mi o le sai gbega titi lai.

You are bigger than the biggest
Response:

Olowogbogboro ti ‘n gba omo re lofin

Response:
A se kabiesi re eladumare tewogbope (Interlude (Omo egbala gbo in so ke).

Oba to ti wa o, k’ aye to wa
ti si tun ma wa nigba ti aye ko no si mo

Mo ni, Oluwa n’ be bi ti ati Jo

Response: A wa la o sin baba bi ta ti jo.

Bridge:
Ologun li OLUWA; OLUWA li orukọ rẹ̀.
ọwọ́ ọtún rẹ li ogo ninu agbara:
ọwọ́ ọtún rẹ fọ́ ọtá tútu.
Emi o kọrin si OLUWA,

Mo korin hallelujah
Mo ke hallelujah
Ona to di ti la o
Oluwa la ona ni bi to ko so na
Ona to di ti la o
Ogo oluwa won la ye mi

Mp3 Video

Debra Crown-Olu – Korin Si Oluwa ft. Laolu Gbenjo (Lyrics, Mp3 Download)

Follow Us On Facebook InstagramTwitter

Similar Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *