Elijah Daniel - Igileyin Ogba Mi

Elijah Daniel – Igileyin Ogba Mi Download (Lyrics, Video, Mp3)

Contents

Download Latest Trending song “Igileyin Ogba Mi” by Elijah Daniel.

Elijah Daniel - Igileyin Ogba Mi
Igileyin Ogba Mi Mp3 Download, Lyrics, Video & Mp4

Nigerian gospel music minister, Elijah Daniel releases “Igileyin Ogba Mi ” off his new album titled Victorious Praise.

Elijah is a prolific songwriter and singer that has inspired so many young artists. His lyrics are said to be sent from heaven as they have the ability to stir even the hardest of hearts to worship and Praise the Almighty God.

Igileyin Ogba Mi talks about God being our pillar in Yoruba language, indeed God is our pillar. Jesus Christ the son of the living God is our backbone, He’s our constant strength when we can’t go on, He is our comforter, our Solace and strength.

Mp3 Download for Igileyin Ogba Mi by Elijah Daniel (E-daniels)

Download Music

Mp4 YouTube Video

Igileyin Ogba Mi Lyrics

owo tosole aye ro
Ti enikeni kole so nipa re
Eri to gbe ile aye duro
tenikeni ole je afi oro nikan
Bi eyin ba mu ile aye yi bioti wuwo to tie fi ala
Owo yi fi omi lasan di mu morun sanmo
bawo ni agabra yin ti po to
Opo todi ile aye mu Opo to saye ro

Opo
Tosole aye mi reo
Opo
Ti oje njapo
Opo
Tosole aye mi reo
Opo
Ti oje njapo
Igileyin ogba mi
Ema se obaba
Igileyin ogba mi
Ema se obaba

Opo
Tosole aye mi reo
Opo
Ti oje njapo
Opo
Tosole aye mi reo
Opo
Ti oje njapo
Igileyin ogba mi
Ema se obaba
Igileyin ogba mi
Ema se obaba

Opo
Tosole aye mi reo
Omi leyin eja mi
Apata ti mo duro le
agbelebu tio je nsubu
Igileyin ogba mi ema se o baba
Igileyin ogba mi ema se o baba

Wo o bati gbagbe mi labule
Anu re lomu mi ja gbangba
Won o ba ti tami soko eru
Anu re lomu mi ja gbangba
Alatileyin mi
ema se o modupe ore
Igileyin ogba mi toduro gbo n
Ema se o baba

Ero ota ni kalo sajo
Ife inu won ni kama pada wale
Wo bose mu mi bori ogun
awon ota mi nrele
agbara re agbara re
agbara re
Lo n gbemi leke
moma dupe o moyin o logo

Opo
Tosole aye mi reo
Opo
Ti oje njapo
Opo
Tosole aye mi reo
Opo
Ti oje njapo
Igileyin ogba mi
Ema se obaba
Igileyin ogba mi
Ema se obaba

Elijah Daniel – Igileyin Ogba Mi Download (Lyrics, Video, Mp3)

Follow Us On Facebook InstagramTwitter

Similar Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *