Monique - Chant (Lyrics, Mp3 Download)

Monique - Chant (Lyrics, Mp3 Download)

Based In African, Nigerian Gospel Music Minister Monique Releases a New Song in September, 2021 Titled “Chant” with Mp3 Download and Lyrics

This Song is an Undiluted Praise Medley that deserves your attention, Available on all digital platforms.

Mp3 Download for Chant by Monique

Download Music

Chant Lyrics

Awimayehun Oba ayeraye
Alagbada nla Oba ti nla ibu aye ja
Fona hanmi ki ma ya sigbo
Oba oni fitila ire
Edumare to tiwaya mi sinu ola imole


Click here to Download Audio


Iwo ni mofeyin ti ti mo tun wo loju
Oju Oluwa o kin deru bani
Baba Oba ti n moba je, Baba Abo, Baba Oba
Baba Bo Baba Agbalagba
Oba Bo, Oba Nla, Oba Abo, Oba Eledumare

Oba to nje mimo
To n wo mimo
O nse mimo
O nsun mimo
O ngbe mimo
Mimo Mimo Loruko re
Yagbo yaju alagbede orun o

Eledumare, Eledumare
Eledumare, Eledumare
Iru kere owo re Ina
Opa owo re ase
Let your will be done in my Life
Kase re bere Lori mi o
Oba mimo

Agbara ra nbe ninu eje Jesu
Ninu eje Jesu Agbara nbe
Ninu eje Jesu Agbara nbe

Oba ti njejo ti Lawyer aye kn itun da
Oda ti Nebukadinesari Ko ma si eni to le yi
Odidi Oba Jeweko fodun meje bi eran

Eru re nba mi o
Eledumare
Ologo meta,Ologo meta,Ologo meta
Titi lai la lai
Nigba ti molo sile Oluwa, Ile Oluwa, Ile Oluwa
Oluwa gbami Oluwa wo mi
ose mi lore
Ose mi lore

Oluwa gbami Oluwa wo mi
ose mi lore
Ose mi lore
Mo dupe o

Mp4 Video

Monique – Chant (Lyrics, Mp3 Download)

Click here to Download Audio
Download Mp3

Leave a Comment

Your email address will not be published.