Spirit of Prophecy - IGBALA

Spirit of Prophecy – IGBALA

Spirit of Prophecy - IGBALA

Spirit of Prophecy has just dropped a new powerful new single , titled “IGBALA”, a song of testimony of every believer, a heartfelt expression of the many gifts that come with the gift of Salvation.

“Igbàlà” is a Yoruba word that carries profound meaning. It translates to “Salvation” in English, but this song represents so much more than just that word. The song is available on YouTube

Spirit of Prophecy – IGBALA Mp3 Download

Download Free Music

Video: IGBALA

IGBALA Lyrics by Spirit of Prophecy

Ofun Mi Ni
Igbala, Iwosan, Ilera, Pipe. 2x

To ba Gbo pe Idemi ja
O ye ko ti O Pe Sekeseke ti bo. 2x

Oluwa Loluso agutan mi
Ohun Oluwa mi ni gbo
Oro Oluwa Iye ni
Oya la eti re ko je ko wole
Oro tin o mu Omo toti sonu
To mu omo yen pade rele.
Faith is my Currency
Oya ka Bible e ko ko fi cash out
(ko fi cash out)
His mercies are new
Every Morning
Oya subscribe ko to step out
(ko to step out)

Nigbati ebi npa mi,
Jesu ni bread of lLife
Jesu je oku dide,
Jesu eternal Life
Jesu funmi ni Alafia,
Lai si ni Nasarawa
Isimi Wa ninu jesu,
Omo ope Oya sarewa
Goodness and mercies dae follow
From now until tomorrow
And everything way I get omo
Na my own me I no borrow.
Ninu aye, Jesu Yomi kuro
O ramipada o wa so mi d’ omo
Mo wa dupe lowo Aye Raye
(aye raye)

Ninu aye, Jesu Yomi kuro
O ramipada o wa so mi d’ omo
Mo wa dupe lowo ayeraye

Ofun Mi Ni
Igbala, Iwosan, Ilera, Pipe. 2x

His Goodness and Mercies
Is Uncountable
Anytime wae Call owa available
In the Presence of enemy
You Prepare a Table
O de je kin wa comfortable.

Ogo, Ogo
Oya gba gbogbo ogo ogo
Iwo le ye lati gba gbogbo
Ola abgbara imo
Ati gbo gbo ogo.

Judah, Judah,
Lion of the tribe of Judah
Awon agbagba mirinlelogun
Wole niwaju re won wa Judah, won wa Judah

Judah, Judah,
Lion of the tribe of Judah
Awon agbagba mirinlelogun
Wole niwaju re won wa Judah.

Aribi Rabata, (Aribi Rabata)
Araba Ribiti, (Araba Ribiti)
Ise ti baba nse kabiti kabiti, kabiti kabiti

Tani, tani, tani, tani,
Emi ma tele (Jesu) 2x

Ofun Mi Ni
Igbala, Iwosan, Ilera, Pipe. 2x

Follow Us On Facebook InstagramTwitter

Similar Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *