Tope Alabi - Eyin Oluwa Hallelujah

Tope Alabi Oluwa O Tobi

Contents

“Tope Alabi Oluwa O Tobi” is a song by Popular and Talented singer and gospel music minister with Mp3, Lyrics, Mp4 and Video Download

This Song is an Undiluted Praise Medley that deserves your attention, Available on all digital platforms.

Tope Alabi Oluwa O Tobi

Mp3 & Audio Download for Tope Alabi Oluwa O Tobi

Download Mp3

Mp4 YouTube Video

Oluwa O Tobi Lyrics

Oluwa o tobi
o tobi o, o tobi ×2
kos’eni tale fi s’afiwe re o
o tobi o, ko s’eda tale fi s’akawe re o
o tobi o oluwa ×2

O tobi o, oluwa giga
lorile ede gbogbo
gbigbega ni o
pupopupo ni o
o koja omi okun
at’osa o ga po
ajulo ose julo

Oba Lori aye o tobi o eh
agbani loko eru
olominira ton deni lorun
ofi titobi gba mi
lowo ogun t’apa obi mi oka
olugbeja mi to ba r’ogun
lalai mu mi lo to segun
Akoni ni o
Boti tobi to oo
lanu re tobi
boti tobi se o
lododo re tobi o
o tobi tife tife
oni majemu ti kii ye
Aro nla to gbo jije minu
aye gbogbo alai le tan
ogbon to koja ori aye gbogbo ooo
akoko otobi, o tobi o

Follow Us On Facebook InstagramTwitter

Similar Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *